OLORUN MO ORUKO MI. O TILE MO IYE IRUN TI O WA LORI MI. NJE IWO LE KA IYE IRUN TI O WA NI ORI RE?* *MATIU 10:30 OLORUN LE SO IYE IRAWO TI O WA NI OJU ORUN. OUN LO FI OKOOKAN WON SI IBI TI WON WA! ** **ORIN DAFIDI 147:4