Page 5 - Yoruba God knows my name
P. 5
OLORUN MO OHUN TI
O NSELE SI MI. O MO
BI INU BA BAJE, TABI
MO NI AYO; IGBA TI
INU NBI MI, TABI TI
NKAN KO DARA.
O NBOJU
TO MI.
SIWAJU KI A TO BIMI,
OLORUN MO OHUN TI YOO
SELE LOJOJUMO SI MI NI
GBOGBO OJO AYE MI.
OLORUN MO O
DAJUDAJU. O SI MO
GBOGBO ENIYAN INU
AYE, ATI WIPE…
...O FERAN
GBOGBO WON.
BIBELI, Nitori Olorun fe araye tobe
ORO OLORUN ge, ti o fi omo bibi re kansoso
KO WA WIPE… funni, ki enikeni ti o ba gba
a gbo ma ba segbe, sugbon
ki o le ni iye ainipekun.
JOHANU 3:16