Page 6 - Yoruba God knows my name
P. 6
OLORUN FERAN WA SIBESIBE,
BI A TILE SE OHUN TI KO DARA.
O PE AWON NKAN TI KO
DARA WONYI
NI ESE.
ENIKENI TI O BA
DESE YOO GBA
*
IJIYA.
SUGBON OLORUN
FERAN WA PUPO
TI O FI…
… RAN OMO RE, JESU,
LATI JE IYA TI OYE
*ROMU 6:23
KI AWA JE.
O KU SUGBON
O TI JI DIDE KURO
NI IPO OKU.**
BI O BA GBA JESU
BI OLUGBALA RE, IWO
**JOHANU 11:25 YOO LE GBE PELU RE
NI ORUN TITI AYERAYE.