OLORUN RI MI NIGBATI
MO JADE LO LATI SERE,
ATI NIGBATI MO
LO SUN.*
OUN LE BOJU TO
MI NITORI OUN
KII SUN. **
*ORIN DAFIDI 139:1-16
**ORIN DAFIDI 121:3-4
NIGBATI MO FARA
PAMO SI KORO TI
MO FERAN JU,
OLORUN N
RI MI!
KOSI ENIKAN TI
O LE SAPAMO
FUN OLORUN.