Page 7 - Yoruba God knows my name
P. 7
OYA, BA OLORUN
SORO BAYI KI O WIPE,
OLORUN, MO DUPE
FUN OPOLOPO IFE TI O
NI SIMI. MO MO WIPE
MO TI SE NKAN TI
KO DARA,
O SI DUNMI. *
MO DUPE LOWO RE
PE O RAN JESU LATI
JE IYA ESE MI.
JOWO DARIJI MI,
KI O WA SINU AYE
MI, LATI RANMI LOWO
KI NLE MA A FERAN RE
SIWAJU SI LOJOJUMO.**
AMIN.
*ISE AWON APOSTELI 3:19
** JOHANU 14:23, MATIU 28:20